language
string
goal
string
solution0
string
solution1
string
label
int64
Yoruba
Kí ni a lè fi gbẹ́ ilẹ̀?
Jígà ni a lè fi gbẹ́ ilẹ̀
Àdá ni a lè fi gbẹ́ ilẹ̀
0
Yoruba
Àwọn àgbẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nílò irinṣẹ́ pàtàkì kan, kí ni irinṣẹ́ náà?
Ọkọ ni irinṣẹ́ pàtàkì tí àwọn àgbẹ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nílò
Katakata ni irinṣẹ́ pàtàkì tí àwọn àgbẹ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nílò
1
Yoruba
Ohun tí mo lè fí pọnmi lọ sí ilé-ìwẹ̀ ni
Garawa ni màá lò láti pọnmi lọ sí ilé-ìwẹ̀
Ọ̀bẹ ni màá lò láti pọnmi lọ sí ilé-ìwẹ̀
0
Yoruba
Tí mo bá fẹ́ pe ènìyàn tí n kò rí, kí ni màá lò?
Ẹ̀rọ-ìfọṣọ ni màá lò láti pe ẹni tí n kò rí
Ẹ̀rọ-ìléwọ́ ni màá lò láti pe ẹni tí n kò rí
1
Yoruba
Orí ibo ni wọ́n máa ń gbé àtùpà sí nígbà kan?
Orí abọ́ ìjẹun
Orí pẹpẹ
0
Yoruba
Ibo ni mo ti lè gbà owó pẹ̀lú káàdì ìyọwó?
Ẹnu Ẹ̀rọ-ìléwọ́
Ẹnu Ẹ̀rọ-apọwó
1
Yoruba
Kí ni màá fi gbowó lẹ́nu Ẹ̀rọ-apọwó?
Kàádì ayọwó
Kàádì ìdánimọ̀
0
Yoruba
Nígbà tí n kò bá mọ ọ̀nà mọ́, kí ni mo le lò?
Àwòrán ni màá lò
Atọ́ka-ọ̀nà ni màá lò
1
Yoruba
Láti ya àwòrán àdánìkanyà tí ó dúró rẹ́gí, kí ni màá lò?
Ẹ̀mú Ayàwòrán ni màá lò
Àga ìrọ̀gbọ̀kú ni màá lò
0
Yoruba
Tí ojú bá ń dun ènìyàn tí kò sì rína dáadáa , kí ni dókítà yóò pèsè fún un?
Dígí ni dókítà yóò pèsè fún un
Awò ni dókítà yóò pèsè fún un.
1
Yoruba
Kí ni a lè lò láti lọ aṣọ kí ó ba lè dán?
Òkúta ni a lè lò
ẹ̀rọ Ìlọṣọ ni a lè lò
1
Yoruba
Orí ibo ni àwọn Yorùbá ti máa n dáná?
Orí àpótí
Orí àrò
1
Yoruba
Kí ni ìbọn ọdẹ nílò láti ṣiṣẹ́?
Omi ni ìbọn ọdẹ nílò láti ṣiṣẹ́
Ẹtù ni ìbọn ọdẹ nílò láti ṣiṣẹ́
1
Yoruba
Láti wọn nǹkan déédéé nínú ọjà, ọlọ́jà gbọ́dọ̀ ni kí ni?
Ọlọ́jà gbọ́dọ̀ ni ẹ̀mú
Ọlọ́jà gbọ́dọ̀ ní òṣùwọ̀n
1
Yoruba
Kí ni ẹkùn màá ń fi gé ẹran tí ó bá pá?
Eyín ọ̀gàn
Ọ̀be
0
Yoruba
Epo pupa máa ń jẹyọ látara kí ni?
Látara èkùrọ́
Látara oyin
0
Yoruba
Èso tí ó dára lati jẹ́ fún àìsùn ni kí ni?
Àgbàdo
Orógbó
1
Yoruba
Láti fọ abọ́ kíákíá ni ayé òde-òní, kí ni màá lò?
Ẹ̀rọ ìfọbọ́ ni mo máa lò
Ẹ̀rọ ìfọṣọ ni mo máa lò
0
Yoruba
Ibi tí ó pín ìlú kan sọ́tọ̀ kúrò lára ìlú mìíràn
ni à ń pè ní ojúde ìlú
ní à ń pè ní ààlà ìlú
1
Yoruba
Ẹran ilé tí ó jẹ́ ìdàkejì àgùntàn
ni a mọ̀ sí ewúrẹ́
ni a mọ̀ sí ajá
0
Yoruba
Kí ni wọ́n ohun èlò ìdáná ni ayé àtijọ́?
Ìkòkò ni ohun èlò ìdáná ni ayé àtijọ́
Àgbá ni ohun èlò ìdáná ni ayé àtijọ́
0
Yoruba
Lára ìlù tí àwọn olórin Jùjú máa ń lù
Èkùtù ni ìlú tí ni àwọn olórin Jùjú máa ń lù
Bàtá ni ìlú ni àwọn Jùjú máa ń lù
1
Yoruba
Kí ni àgbẹ̀ máa ń fi ka ọsàn ni orí igi
Dòjé ni àgbẹ̀ máa ń fi ká ọsàn ní orí igi
Ọ̀kọ̀ ni àgbẹ̀ máa ń fi ká ọsàn ní orí igi
0
Yoruba
Kíni olórin Àpàlà ni ó máa ń lo bíi ìlú?
Apẹrin ni olórin Àpàlà máa ń lò gẹ́gẹ́ bíi ìlú
Gángan ni olórin Àpàlà máa lò gẹ́gẹ́ bíi ìlú
1
Yoruba
Irú ìlù wo ló ni a tún lè lú fún Wákà ní ìlú Ìlọrin?
Bẹ̀m̀bẹ́ ni ìlú tí a tún lè lù fún Wákà ní ìlú Ìlọrin
Abọ́ ni ìlú tí a tún lè lù fún Wákà ní ìlú Ìlọrin
0
Yoruba
Kí ni ohun à ń pe akèrègbè tí a sín ní ìlẹ̀kẹ̀?
Sákárà ni à ń pe akèrègbè tí a sín ní ìlẹ̀kẹ̀
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ni à ń pe akèrègbè tí a sín ní ìlẹ̀kẹ̀
1
Yoruba
Tí mo bá fẹ́ jẹ Àmàlà, kíni máa ṣe?
Màá ro èlùbọ́ mi nínú omi gbígbóná
Màá ro gààrí mi nínú omi gbígbóná
0
Yoruba
Tí mo bá fẹ́ kọrin, kí ni mo le lò gẹ́gẹ́ bíi ìlú?
Agbọ̀n ni mo le lò
Gúdúgúdú ni mo le lò
1
Yoruba
Ohun èlò ìsọ́ra wo ni ènìyàn lè lò pẹ̀lú òkúta nínú rẹ̀?
Katakata ni ohun èlò ìsọ́ra tí ènìyàn lè fi ta òkúta
Akatanpo ni ohun èlò ìsọ́ra tí ènìyàn lè fi ta òkúta
1
Yoruba
Kíni a máa ń ta lójú ogun gẹ́gẹ́ bíi nǹkan ìjà?
Ọrún ni a máa ń ta lójú ogun gẹ́gẹ́ bíi nǹkan ìjà
Ọfà ni a máa ń ta lójú ogun gẹ́gẹ́ bíi nǹkan ìjà
1
Yoruba
Kí ni ọ̀kan lára nǹkan tí àwọn àgbẹ̀ máa ń lò láti ṣọ́ oko wọn lọ́wọ́ ẹranko?
Pàńpẹ́ ni ọ̀kan lára nǹkan tí àwọn àgbẹ̀ máa ń lò láti ṣọ́ oko wọn lọ́wọ́ ẹranko?
Idà ni ọ̀kan lára nǹkan tí àwọn àgbẹ̀ máa ń lò láti ṣọ́ oko wọn lọ́wọ́ ẹranko?
0
Yoruba
Lára àwọn erè oko tí àwọn ẹyẹ fẹ́ràn jùlọ
ni iṣu jẹ́
ni ọkà-bàbà jẹ́
1
Yoruba
Kòkòrò ẹ̀fọn ni a mọ̀ sí
alátagbà àìsàn ibà
aláwòsàn àìsàn ibà
0
Yoruba
Ìpèle wo ni màá kàn lẹ́yìn oyè Ọmọwẹ́?
oyè ọjọ́gbọ́n
oyè akọ́ṣẹ́mọṣẹ́
0
Yoruba
Tí kò bá sí iná ìjọba, kí ni mo lè fi fẹ́ra
Màá lo igi ìdáná láti fi fẹ́ra
Màá lo abẹ̀bẹ̀ láti fi fẹ́ra
1
Yoruba
Kíni a lè fi ya irun ọmọdé?
Òǹyà ni ó dára jù
Ìṣánà ni ó dára jù lọ
0
Yoruba
Ohun pàtàkì tí a fi máa ń dá olóyè mọ̀
Ni àdá ọrùn wọn
Ni ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn wọn
1
Yoruba
Báwo ni a ṣe le gbẹ́ kàǹga fún amù lílò?
A ó gbẹ ní òbìrìkìtì/òbírípo
A ó gbẹ ní onígun mẹ́ta
0
Yoruba
Kí ni o máa ń sẹ̀ ní òwúrọ̀ kùtùkùtù?
Òjò ni ó máa ń sẹ̀
Ìrì ni ó máa ń sẹ̀
1
Yoruba
Ataalẹ̀ jẹ́ èròjà fún oúnjẹ wo
Iyán tí a fi iṣu ṣe
Ògì tí a fi bàbà tàbí àgbàdo ṣe
1
Yoruba
Níbo ni a máa ń di ajílẹ̀ sí ?
Inú aṣọ ìwọ̀sùn ni a máa ń di ajílẹ̀ sí
Inú àpò ni a máa ń di ajílẹ̀ sí
1
Yoruba
Yàtọ̀ sí ẹní, kí ni mo tún le fi sùn nínú yàrá
Odó ni mo tún le fi sùn nínú yàrá
Ibùsùn ni mo tún le fi sùn nínú yàrá
1
Yoruba
Ọkàn pàtàkì ní yàrá ìjẹun ni
Pátákó jẹ́ fún ènìyàn
Tábìlì jẹ́ fún ènìyàn
1
Yoruba
Ibo ni a ti ń dáná nínú ilé?
Ìyàrá ìbùsùn ni a ti ń dáná nínú ilé
inú Ìyàrá ìdáná ni ati ń dáná nínú ilé
1
Yoruba
Tani olórí ilé ní ilẹ̀ Yorùbá?
Ọmọ ni olórí ilé ní ilẹ̀ Yorùbá
Bàbá ni olórí ilé ní ilẹ̀ Yorùbá
1
Yoruba
Báwo ni a ṣe ń kíni ní àárọ̀?
Ẹkáàárọ̀ ni à ń kíni ní àárọ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá
Ẹkáalẹ́ ni à ń kíni ní àárọ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá
0
Yoruba
Kíni a fi ń já ọbẹ̀ Ewédú?
Ìgbálẹ̀ ni a fi ń já ewédú
Ìjábẹ̀ ni a fi ń já ewédú
1
Yoruba
Kíni a fi ń lọ̀ ata
Òkúta ni a fi ń lọ ata
Ẹ̀rọ ìlọta ni a fi ń lọ ata
1
Yoruba
Báwo ni a ṣe ń kí onídìrí?
Ojú gbooro ni ọ̀rọ̀ tí à ń sọ láti fi kí ònídìrí
Tí a bá fẹ́ kí ònídìrí, Irun ṣíṣe ní a ma sọ
1
Yoruba
Kíni àwọn àgbẹ̀ fi ń ro oko?
apẹ̀rẹ̀ ní àwọn àgbẹ̀ fi ń ro oko
Àdá ní àwọn àgbẹ̀ fi ń ro oko
1
Yoruba
Kíni ìlò àga?
Àga wà fún ìtolé
Àga wà fún ìjókòó
1
Yoruba
Báwo ni a ṣe ń tọjú ìbùsùn
A ma ń tọ́jú ìbùsùn nípa sísùn le bẹ́ẹ̀
A ma ń tọ́jú ìbùsùn nípa títẹ ẹ
1
Yoruba
Kíni ìwúlò ìsaasùn?
Fún ọbẹ̀ sísè
Fún abọ́ fífọ̀
0
Yoruba
Irú ìlù wo ni ó tóbijù
Ìyá ìlù jẹ́ irú ìlù tí ó tóbijù
Irú ìlù tí ó tóbijù ni Sákárà
0
Yoruba
Kíni ẹ̀rọ ìgbàlódé ti ó ń mú ǹkan tutù
Ìkòkò jẹ́ ohun èlò ìgbàlódé tí ó ń mú ǹkan tutù
Ẹ̀rọ amú ǹkan tutù jẹ́ ohun èlò ìgbàlódé tí ó ń mú ǹkan tutù
1
Yoruba
Àwọn wo ni wọ́n ń gbìn oúnjẹ fún ìlú?
Àwọn onídìrí ni wọ́n ń gbìn oúnjẹ fún ìlú
Àwọn àgbẹ̀ ni wọ́n ń gbìn oúnjẹ fún ìlú
1
Yoruba
Kíni à ń fi àdá ṣe?
À ń fi àdá ro oko
À ń fi àdá dáná
0
Yoruba
Àwọn wo ni à ń kíní àroko bọ́dúndé
Àwọn àgbẹ̀
Àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà
0
Yoruba
Nígbàtí àwọn ọkùnrin bá gẹ fìlà ní ilẹ̀ Yorùbá kíni àwọn obìnrin yóò wé?
Àwọn obìnrin yóò wé gèlè nígbàtí àwọn ọkùnrin bá gẹ fìlà ní ilẹ̀ Yorùbá
Àwọn obìnrin yóò wé Fìlà nígbàtí àwọn ọkùnrin bá gẹ̀ fìlà ní ilẹ̀ Yorùbá
0
Yoruba
Bojúbojú jẹ́ eré kíni
Eré ọmọdé
Eré àgbàlagbà
0
Yoruba
Kíni à ń lò dípò ààrò ní ayé òde òni
Àdògán ni à ń lò dípò ààrò ní ayé òde òni
Gáàsì ni à ń lò dípò ààrò ní ayé òde òni
1
Yoruba
Àjọ jẹ́ ọ̀nà tí à ń gbà ṣe kíni
Ọ̀nà tí à ń gbà tọ́jú owó
Ọ̀nà tí à ń gbà ṣe ayẹyẹ
0
Yoruba
Kíni à ń ṣe ní ayẹyẹ ìgbéyàwó?
À ń mú inú ara wa dùn
À ń so ọkùnrin àti obìnrin papọ̀ láti di tọkọtaya
1
Yoruba
Kíni iṣẹ́ agbẹ́gilére
Wọ́n ma ń fọ̀ aṣọ
Wọ́n ma ń gbé igi láti sọ́ ọ di ère
1
Yoruba
Eré ìdárayá wà fún taani?
Eré ìdárayá wà fún gbogbo èyàn
Eré ìdárayá wà fún gbogbo okùnrin
0
Yoruba
Ibo ni à ń tọ́jú owó sí ní ayé òde òni
Inú ìwé ni à ń tọ́jú owó sí ní ayé òde òni
Ilé ìfowópamọ́ sí ni à ń tọ́jú owó sí ní ayé òde òni
1
Yoruba
Ní ilẹ̀ Yorùbá kíni ọkùnrin gbọ́dọ̀ ṣe tí ó bá fẹ́ kí àgbàlagbà?
Ọkùnrin gbọ́dọ̀ sùn sílẹ̀
Ọkùnrin gbọ́dọ̀ dọ̀bálẹ̀
1
Yoruba
Aṣọ taani bùbá àti ṣókótó jẹ́ ní ilẹ̀ Yorùbá?
Aṣọ Obìnrin ni bùbá àti ṣókótó jẹ́ ní ilẹ̀ Yorùbá
Aṣọ Ọkùnrin ni bùbá àti ṣókótó jẹ́ ní ilẹ̀ Yorùbá
1
Yoruba
Aṣọ wíwọ̀ wà fún kíni?
Oge síṣe ni aṣọ wíwọ̀ wà fún
àrà dídá ni aṣọ wíwọ̀ wà fún
0
Yoruba
Òwe pípa wọ́pọ̀ láàárín àwọn wo?
Ààrín àwọn Àgbàlagbà
Ààrín àwọn ọmọdé
0
Yoruba
Ibo ni a ma ń tọ́jú àwọn ohun èlò ìdáná sí?
Yàrá ìdáná ni a máa ń tọ́jú àwọn ohun èlò ìdáná sí
Yàrá ìgbafẹ́ ni a ma tọ́jú àwọn ohun èlò ìdáná sí .
0
Yoruba
Ní àtijó, ibo ni à ń kó erù sìí nínú yàrá ìbùsùn
A máa ń kó erù sí Orí ilé ní àtijọ́
Orí àjà nínú yàrá ibùsùn ni a ma ń kó erù sìí ní àtijọ́
1
Yoruba
Tani olórí agboolé?
Olórí ẹbí ní olórí agboolé
Olórí agboolé ni Bàbá ilé
0
Yoruba
Kíni a fi ń kó abọ́ sí nínú yàrá ìdáná?
Apẹ̀ẹ̀rẹ̀ abọ́ ni à ń kó abọ́ sí nínú yàrá ìdáná
Orí àpáta ni à ń kó abọ́ sí nínú yàrá ìdáná
0
Yoruba
Èyàn mélòó ni ó ma ń ta eré ayò?
Èyàn púpọ̀ ni ó máa ń ta eré ayò
Èyàn méjì ni ó ma ń ta eré ayò
1
Yoruba
Báwo ni àwọn obìnrin ṣe ń gbé ọjà wọn tí wọn ba ń kiri ọjà?
Wọn ma ń gbe lé orí ti wọ́n bá ń kiri ọjà
Wọ́n ma ń gbe lé èjìká tí wọ́n bá ń kiri ọjà
0
Yoruba
Irú ẹ̀rọ amúnáwá wo ni ó ń lo epo?
Ẹ̀rọ amúnáwá tí ó ń lo epo ni jẹnẹrátọ̀
Ọ̀kadà ni ẹ̀rọ amúnáwá tí ó ń lo epo
0
Yoruba
Tí ènìyàn bá fẹ́ lo òògùn, kíni yóò fi lòó?
Ọtí ni ènìyàn yóò fi lo òògùn
Ọmí ni ènìyàn yóò fi lo òògùn
1
Yoruba
Àwọn wo ni ó ń wọ Dànṣíkí ní ilẹ̀ Yorùbá?
Àwọn obìnrin ni ó ń wọ Dànṣíkí ní ilẹ̀ Yorùbá
Ní ilẹ̀ Yorùbá àwọn obìnrin ni ó ń wọ Dànṣíkí
1
Yoruba
Kíni ẹ̀rọ ìgbàlódé tí à ń lò fún aṣọ fífọ̀ ní ayé òde òni?
Ẹ̀rọ ìlọta ni ẹ̀rọ ìgbàlódé tí à ń lò fún aṣọ fífọ̀ ní ayé òde òni
Ẹ̀rọ ìfọṣọ ni ẹ̀rọ ìgbàlódé tí à ń lò fún aṣọ fífọ̀ ní ayé òde òni
1
Yoruba
Irú ìkòkò wo ni à ń lò fún iná dídá tí ó pọ̀?
Ìkòkò kékeré ni à ń lò fún iná dídá tí ó pọ̀
àdògań ni à ń lò fún iná dídá tí ó pọ̀
1
Yoruba
Kíni a lè lò sí ohun ọ̀gbìn kí o ba lè hù dáadáa?
Ajílẹ̀ ni a lè lò sí ohun ọ̀gbìn
Èèpẹ̀ ni a lè lò sí ohun ọ̀gbìn
0
Yoruba
Ìró àti bùbá jẹ́ aṣọ tí a mọ̀ mọ́ àwọn wo?
Ójẹ́ aṣọ tí a mọ̀ mọ́ àwọn ọkùnrin ní ilẹ̀ Yorùbá
Àwọn obìnrin ní ilẹ̀ Yorùbá ni a mọ ìró àti bùbá mọ́
1
Yoruba
Kíni ó sábà máa ń wáyé ní iwájú ààfin ní alẹ́
Eré ṣíṣe má ń sábà wáyé níwájú ààfin ní alẹ́
Ọjà alẹ́ ni ó sábà máá wáyé níwájú ààfin ní alẹ́
1
Yoruba
Pàtẹ́wọ́ jẹ́ irú irun tí àwọn wo ń ṣe?
Pàtẹ́wọ́ jẹ́ irú irun tí àwọn ọkùnrin ń ṣe
Pàtẹ́wọ́ jẹ́ irú irun tí àwọn obìnrin ń ṣe
1
Yoruba
Ewé wo ni a maa ń já lé olóyè titun ní orí
Ewé ọ̀gẹ̀dẹ̀ ni a má já lé olóyè titun ní orí
Ewé akòko ni a má ń já lé olóyè titun ní orí
1
Yoruba
Báwo ni o ṣe lè kí àgbàlagbà gẹ́gẹ́bí obìnrin
Gégé bí obìnrin wàá kúnlẹ̀ kí àgbàlagbà
Gégé bí obìnrin wàá dọbalẹ kí àgbàlagbà
0
Yoruba
Kíni a fi ń mọ kóló?
Amọ̀ ni a fi ń mọ kóló
Àpò ni a fi ń mọ kóló
0
Yoruba
Kíni a fi ń gbá ilẹ̀ tí ó dọ̀tí
omi ní a fi ń gbá ilẹ̀ tí ó dọ̀tí
ìgbálẹ̀ ní a fi ń gbá ilẹ̀ tí ó dọ̀tí
1
Yoruba
Kíni ìwúlò ṣíbí
Ṣíbí wúlò fún eré ṣíṣe
Ṣíbí wúlò fún oúnjẹ jíjẹ
1
Yoruba
Báwo ni a ṣe ń kí Ọba ìlú?
Kábíyèsí o
Ẹkáàárọ̀ sà
0
Yoruba
Tí a bá fẹ́ gúnyán ní ilé Yorùbá kíni a máa lò?
Abọ́ ni a ma fi gúnyán ní ilẹ̀ Yorùbá
Odó àti ọmọ odọ́ ni a ma fi gúnyán ní ilẹ̀ Yorùbá
1
Yoruba
Kíni a fi ń hun aṣọ òkè?
Òwú ni a fi ń hun aṣọ òkè
Okùn ni a fi ń hùn aṣọ òkè
0
Yoruba
Yàtọ̀ sí owó, kíni atún le tọ́jú sí ilé ìfowópamọ́?
Ohun àlùmọ́ọ́nì ni a tún le tọ́jú sí ilé ìfowópamọ́ sí yàtọ̀ sí owó
aṣọ ni a tún le tọ́jú sí ilé ìfowópamọ́ sí
0
Yoruba
Kíni a fi ń kọ oúnjẹ?
Ìgbákọ ni a fi ń kọ oúnjẹ
À ń fi Igi kọ oúnjẹ
0
Yoruba
A le fi awon ohun elo wonyii se ajile fun ogba ile wa
Ìràwé, irin, ìgbẹ́ adìyẹ
Ìràwé, ẹpo eyin, ìgbẹ́ adìyẹ
1
Yoruba
kí ni a le fi gbe awọn èrè oko lati oko
a lè lo apẹ̀ẹ̀rẹ̀
a lè lo igbá omi
0
Yoruba
irú bàtà wo ni ènìà nílò lati fi gun orí òkè?
bàtà ìṣere
bàtà tí o nípọn
1
Yoruba
O fẹ́ mọ aago tí o lu, kí ni ohun to tọ́ láti wò?
aago ọwọ́
aago orí
0
Yoruba
O fẹ́ sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n rẹ tó wà ní ilú mìíràn, kí ni ohun tó yẹ ki o lò?
ẹ̀rọ alágbèékà rẹ
ẹ̀rọ aṣíye rẹ
0